Jump to content

Òdòdó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwọn orísirísi òdòdó.

Òdòdó, ti a mo nigba miran bi ìtànná ewéko, ni eyi to ni ibi atunbi ninu awon ogbin olododo (awon ogbin ti a mo si Magnoliophyta, tabi angiosperms). Ise aaye ododo ni lati kopa ninu atunbi nipa wiwa ona lati mu omiepon wa ba awon eyin.