Ògbóni

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ògbóni ní ilẹ̀ Yorùbá, jẹ́ àkójọpọ̀ àwùjọ àwọn àgbààgbà tí wọ́n ń ṣe àmójútó ètò ìjọba ìlú.[1] Àwọn Ògbóni bákan náà tún jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn àgbàlagbà abẹnugan ìlú tí iṣẹ́ wọn dá lórí ṣíṣe òfin tí ìlú yóò ma tẹ̀lé. Ẹ̀wẹ̀, wòn tún ma ń yan ọmọ Oyè, wọ́n sì tún ma ń bỌ́ba dámọràn lórí bolí ìlú yóò ṣe tùbà tí yóò sì tùṣẹ. ohún tó so àwọn ògbóni pọ̀ ni Ẹdan tíí ṣe (ìyá tó bì ilẹ̀) tí ó sì so wọ́n pọ̀ bí ìmùlẹ̀ tí wọn kìí fi ń da ara wọ́n. Wọ́n ní ìlànà àti òfin tiwọ́n tí ó kín wọn lẹ́yìn tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi lágbára púpọ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá ní ayé àtijọ́, pàá pàà jùlọ láàrín àwọn ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti Ìjẹ̀bú.[2]{Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́}}

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ògbóni". Litcaf. 2016-01-16. Retrieved 2019-03-16. 
  2. "Our Mothers, Our Powers, Our Texts". Google Books. Retrieved 2019-03-16.