Òjò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Iji

Òjò

Òjò jẹ́ omi tí ó ń rọ̀ láti sánmọ̀, tí ó ṣì ń di omi ní orí ilẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní ni omi tí ó ń sọ̀kalẹ̀ yí ń ṣe fún ọmọ ènìyàn, kí lára rẹ̀ ni a ti ń pèsè iná mọ̀nàmọ́má, ó lò nínú ilé, ó fún mímu, ìdáná àti ìtọ́jú oúnjẹ, ó ìwẹ̀, I àti bẹẹ bẹẹ lọ. Síwájú sí, a tún ń lọ omi fún àǹfààní àwọn ǹkan ọ̀gbìn wá gbogbo.