Òjògbón
Ìrísí
Ojogbon jé ipò èkó tí o ga jù ní yunifásitì tàbí ilé-èkó miran [1], àwon ojogbon ma ún jé oloye gíga/pupo ní aaye èkó won [2], kí ènìyàn tó Le di ojogbon, o gbodo kókó keko láti di Dokita tí ìmòye(PhD) [3]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Definition of PROFESSOR". Merriam-Webster. 2022-02-13. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ "professor". Etymology, origin and meaning of professor by etymonline. Retrieved 2022-03-02.
- ↑ "What is a Professor? : Professors and professorship: origins and history". Professors and professorship. Retrieved 2022-03-02.