Dokita(PhD)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Dokita(PhD) tí a tún mò sí Dokita tí ìmò òye jé ara àwon ipò èkó tí o ga jù ní yunifásitì tàbí ilé èkó míràn, o jé oyè-ekó tí ènìyàn ma ún sé iwádí tó dájú ní èka èkó rè tí o to le ri gba [1]. Òpòlopò ipò akeko ní yunifásitì àti ilé-èkó giga olodun merin miran ní lò oludije akeko láti ní Dókítá ìmò òye kí won tó le gba sísé, ósì tún jé ipò tí ènìyàn gbodò ní ní òpòlopò igba tí o tó le di ojogbon [2].

Otún le ka eyi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Òjògbón

• Dókítá Onisegun

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "What are the Criteria for a PhD?". www.FindAPhD.com. Retrieved 2022-03-03. 
  2. Muniz, Hannah (2022-01-16). "The 19 Steps to Becoming a College Professor". Online SAT / ACT Prep Blog by PrepScholar. Retrieved 2022-03-03.