Òkun Índíà
Ìrísí
Òkun Índíà ni Òkun Eleketa ti o tobi Ju lo ni Àgbáyé lehin Òkun Atlántíkì, ati okun Pasifiki. Ni iha Iwo Orun si okun naa, ni Orile erekusu Afrika,ni iha Ila Orun si okun naa si ni apa Ila orun-Guusu orile erekusu Asia.Si ariwa okun naa ni apa guusu Asia. Orile ede ti o tobi ju lo, Ninu awon orile ede ti o wa ni iha naa ni orile ede India, nibi ti okun naa ti mu oruko, tabi ti okun naa f'oruko jo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |