Òrò àyálò Yorùbá
Ìrísí
Ọ̀rọ̀-àyálò jẹ́ ọ̀rọ̀ kan Pàtàkì tí a yá wọnú èdè Yorùbá láti inú èdè mìíràn, ó le jẹ̀ láti inú Gẹ̀ẹ́ṣì, Lárúbáwá, Haúsá àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kí ó lè bá ohun tí wón fẹ́ mu nínú èdè won.[1][2]
Àkíyèsí sí wà pé kò sí èdè tàbí àwùjọ kan tí kì í ya ọ̀rọ̀ láti inú èdè kan, bí Gẹ̀ẹ́ṣì ṣe yá ọ̀rọ̀ bẹẹ náà ni àwùjọ Yorùbá náà yá ọ̀rọ̀, bí ó sì ṣe wà káàkiri nínú gbogbo èdè àgbáyé.
Oríṣiríṣi Ọ̀nà méjì làá gbà yá ọ̀rọ̀ lò nínú èdè Yorùbá.
1) Àfetíyá
2) Àfojúyá
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Borrowed Words". Rice University -- Web Services. Retrieved 2020-03-03.
- ↑ "ORO AYALO". YORUBAOLOJI. 2016-11-18. Retrieved 2020-03-27.