Ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Patrick Olusegun Odegbami | ||
Ọjọ́ ìbí | 27 Oṣù Kẹjọ 1952 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Abeokuta, Nigeria | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1970–1984 | Shooting Stars | - | (-) |
National team | |||
1976–1982 | Nigeria | 46 | (23) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Patrick Olúṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí tàbí Ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1952 (August 27, 1952) jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Abẹ́òkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ipò iwájú agbábọ́ọ̀lù sáwọ̀n ni ó máa ń gbá.[1] [2] [3] [4] Lọ́dún 2015, ṣẹ́gun Ọdẹ́gbàmí dára pọ̀ mọ́ Òṣèlú, ó sìn díje dupò Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn lọ́dún 2019, ṣùgbọ́n ìbò abẹ́lé kò gbè é. [5]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:NFT player
- ↑ "Segun Odegbami biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 1952-08-27. Retrieved 2020-01-09.
- ↑ "Segun Odegbami". Transfermarkt (in Èdè Jámánì). Retrieved 2020-01-09.
- ↑ "Segun Odegbami Bio, Stats, and Results". Olympics at Sports-Reference.com. 2017-12-18. Retrieved 2020-01-09.
- ↑ Published (2015-12-15). "2019: Segun Odegbami declares Ogun gov bid". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-09.