Ṣẹ́gun Agbájé
Ìrísí
Ṣẹ́gun Julius Agbájé | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Olúṣẹ́gun Agbájé Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | Banker, entrepreneur |
Ìgbà iṣẹ́ | 1991-Present |
Gbajúmọ̀ fún | GTBank executive |
Olúṣẹ́gun Agbájé tí wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ alákòóso àti olùdarí ilé ìfowó-pamọ́ Guaranty Trust Bank ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó tún jẹ́ adarí fún ìgbìmọ̀ MasterCard Advisory Board ti àrin gbùngbùn ilà Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Mr. Segun Agbaje - Managing Director/CEO". Retrieved 14 January 2017.