Ẹ̀ùkáríọ́tì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Eukaryotes
Ẹ̀ùkáríọ́tì
Scientific classification
Domain: Eukaryota
Whittaker & Margulis,1978
Kingdoms
Animalia – Ẹranko
Fungi – Èbu
Plantae – Ọ̀gbìn
Alternative phylogeny

Ẹ̀ùkáríọ́tì tabi ahamo eukarioti je awon ohun elemin[1] ti awon ahamo ara won ni koroonu ninu. Eyi lo ya won soto si pròkáríọ́tì, ti ahamo won ko ni koroonu. [2]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Eukaryote". ScienceDaily. 2018-05-19. Retrieved 2018-05-20. 
  2. "Eukaryote - biology". Encyclopedia Britannica. 2018-05-10. Retrieved 2018-05-20.