Ẹ̀jẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bleeding finger.jpg

Ẹ̀jẹ̀ ni asàn tó ń lọ yípo nínú ara tó ń gbé àwọn ohun tó ṣe pàtàkì lọ sí inú àhámọ́ ara - fún àpẹrẹ ìbọ́ àti èémí.[1]Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "blood - Definition, Composition, & Functions". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-04-19.