Ẹ̀rọ Ìbánisọ̀rọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹ̀rọ Ìléwọ́ Ìbánisọ̀rọ̀ jẹ́ ohun èlò ẹ̀rọ ìgbàlódé tí ẹni méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ lè fi bá ara wọn sọ̀rọ̀, yálà nípa ohùn tàbí ìkọ̀wé ránṣẹ́ sí ara wọn, bí wọ́n bá tilẹ̀ wà lọ́nà jíjìnnà réré sí ara wọn. Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ tí ẹ̀rọ yìí wà fún ìbánisọ̀rọ̀ nìkan, ṣùgbọ́n ìmọ̀ tí gorí ìmọ̀, Ẹ̀rọ Ìléwọ́ Ìbánisọ̀rọ̀ tí wà fún oríṣiríṣi nǹkan ju ìbánisọ̀rọ̀ lásán lọ. [1] [2]


Ìtàn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìgbàgbọ́ lóri ìwáríì ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ dúró sí àríyànjìyàn. Pẹ̀lú òmíràn ìwári n lá irú bí Tẹlefisan, ínà gílóbù àti kọmuputa. OríṣiríṣI àwọn oludàsìlẹ́ tó ṣe aṣájú iṣẹ́ idánwò lóri àtagbà ohùn lóri okùn-irin àti àtún-ṣe lóri ìrò ọ̀kọ̀ọ̀kan míiràn. Antonio Meucci, Johann Philipp Reis, Elisha Gray, Alexander Graham Bell àti Thomas Edison, nínú àwọn omìíran, gbogbo wọ́n tí gbá iyin pẹ̀lú iṣẹ́ aṣájú lóri Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀.

Ìtan ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rò jẹ́ èyí tí ó ní àńyànjìyàn, tí o dàbarú ira ti ẹ̀tọ́. Ìpasẹ àkópọ̀ àwọn ẹ̀jọ́ ni wọ́n fí pinnu àwọn ère silẹ̀ nígbangba fún àwọn ènìyàn. Àwọn Bell àti Edison ní wọ́n dá púpọ̀ nínu ìtàn ẹ̀ro ìbánisọ̀rọ̀.


Ìwúlò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó wúlò nígbà tí nńkan àìbámọ̀ bá ń ṣẹ lẹ̀

Ó n gbà ènìyàn là nínù ewu.

Ó dín kùn ìgbà tí ènìyàn fí ń kọ lẹ́tà sí ẹnìkejì

Ó dara làtí fí kan sárá sí ènìyàn.

Ìṣòro rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó le láti mó jú tó

Ó maa ń tètè bà jẹ́ ó ní owo lórí

IPARI: Ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ dára fún gbogbo iṣẹ́ láti fig be gòkẹ̀, ó sì dára fún ọ rọ̀ ajẹ́ ilẹ̀ waa.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Srivastava, V.M.; Singh, G. (2013). MOSFET Technologies for Double-Pole Four-Throw Radio-Frequency Switch. Analog Circuits and Signal Processing. Springer International Publishing. p. 1. ISBN 978-3-319-01165-3. https://books.google.com/books?id=fkO9BAAAQBAJ&pg=PA1. Retrieved 2020-01-06. 
  2. "Meet the man who invented the mobile phone". BBC News. 2010-04-23. Retrieved 2020-01-06.