Jump to content

Ẹ̀sìn Krìstẹ́nì ní Guinea-Bissau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ilé ìsìn kan ní Bissau

Àwọn KrìstẹnìGuinea-Bissau jẹ́ ìdásímẹ́wàá (~153,300) àwọn olùgbé Guinea-Bissau (1,533,964[1] - ní 2009). Àwọn ìwádìí mi fihàn pé àwọn àwọn Krìstẹ́nì ní Guinea-Bissau may tó láàrin ènìyàn márùn-ún nínú ọgọ́rùn-ún sí ènìyàn mẹ́tàlá nínú ọgọ́rùn-ún àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè náà.[2]

Guinea-Bissau nìkan ni orílẹ̀ èdè tí àwọn Mùsùlùmí pọ̀ sí nínú àwọn orílẹ̀ èdè tí ó ń sọ èdè Portuguese. Àwọn Krìstẹ́nì Guinea Bissau jẹ́ ará ìjọ Roman Catholic Church (pẹ̀lú àwọn olùgbé Guinea-Bissau tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Portuguese) àti àwọn ìjọ mìíràn.[2] Àwọn Krìstẹ́nì pọ̀ ní ìlú Bissau àti àwọn ìlú mìíràn.[2]

Ìjọba orílẹ̀ èdè Guinea-Bissau gba àwọn oníwàásù ìhìnrẹrẹ láti orílẹ̀ èdè mìíràn láti wàásù ní orílẹ̀ èdè náà láì ní ìdáwọ́ dúró.[2]

Òfin orílẹ̀ èdè náà fi àyè fún ètọ́ fún ẹ̀sìn tí ó wu olúkúlùkù.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. The World Factbook
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 International Religious Freedom Report 2007: Guinea-Bissau. United States Bureau of Democracy, Human Rights and Labor (September 14, 2007). This article incorporates text from this source, which is in the public domain.