Jump to content

Bissau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bissau
Coat of arms of Bissau
Coat of arms
Country Guinea-Bissau
RegionBissau Autonomous Sector
Area
 • Total30 sq mi (77 km2)
Population
 (2007)
 • Total407,424 est.
 • Density13,704/sq mi (5,291.2/km2)

Bissau ni oluilu orile-ede Guinea-Bissau. Ni 2007 iposieniyan re je 407,424 gege bi Instituto Nacional de Estatística e Censos se so.[1]