Victoria, Ṣèíhẹ́lẹ́sì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Victoria, Seychelles)
Jump to navigation Jump to search
Victoria
Skyline of Victoria
Location of Victoria on Mahé Island
Location of Victoria on Mahé Island
Country Seychelles
Island Mahé
Agbéìlú (2002)
 • City 24,970
 • Metro 72,000
Victoria's centrally located clock tower

Victoria (nigba miran won npe ni Port Victoria) ni oluilu ile Seychelles (oun ni oluilu Afrika to kerejulo). O budo si egbe ariwa-apailaorun erekusu Mahé, to je erekusu gbangba ni isupoerekusu na. Ilu na koko je didasile bi ibujoko ijoba alamusin Britani. Ni 2009, olugbe re je 25,000 (fun Victoria Berekete, lmupo mo awon itosi-ilu), ninu apapo olugbe 84 000. Victoria ni Papa Ofurufu Akariaye Seychelles (to je pipari ni 1971.)


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]