Ẹ̀tọ́ ìbò fún gbogbo ènìyàn
Jump to navigation
Jump to search
Ẹ̀tọ́ ìbò fún gbogbo ènìyàn ṣe ẹ̀tọ́ ìdìbò fún gbogbo ọmọ ìlú tó jẹ́ àgbàlagbà, láìkàsí ọlà, ìpawọ́, akọmbábo, ipò láwùjọ, ẹ̀yà ènìyàn, ẹ̀yà èdè, tàbí ìdínà míràn.[1][2]
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Universal suffrage definition and meaning | Collins English Dictionary". www.collinsdictionary.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-02-01.
- ↑ Suffrage, Encyclopedia Britannica.