Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin Rivers Angels
Full name | Rivers Angels Football Club |
---|---|
Founded | 1986 |
Ground | Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Owner | Government of Rivers State (since 1991) |
Manager | Edwin Okon |
League | Nigerian Women's Championship |
Ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin Rivers Angels tí a kọ́kọ́ mọ̀ nígbà kan ní Larry Angels F.C.) jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin Nigeria tí ó fìkalẹ̀ sí ìlú Port Harcourt, ní Ìpínlẹ̀ Rivers.[1][2] Wọ́n ń gba bọ́ọ̀lù-díje ní líìgì àgbábuta ìdíje ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù-díje obìnrin abala àkọ́kọ́ tí Nigeria.[3][4][5][6]
Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹgbẹ́ náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọba Lawrence Ezeh tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Mbaise ní Ìpínlẹ̀ Ímò ni ó dá ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí LARRY Angels lọ́dún 1986.[7] Lọ́dún 1991, ìjọba Ìpínlẹ̀ Rivers gbàkóso ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin náà nípa akitiyan ìyàwó gómìnà ìgbà náà, Arábìnrin Abbe. Wọ́n pegedé nínú ìdíje àwọn obìnrin nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìdíje bọ́ọ̀lù àwọn obìnrin nínú àwọn ìdíje National Sports Festival lọ́dún 1989 ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Bákan náà wọ́n gba ife-ẹ̀yẹ ìdíje ifẹ àkọ́kọ́ tí Ọba, Olu of Warri dá sílẹ̀ ní Warri, ní Ìpínlẹ̀ Delta. Chioma Ajunwa tí ó jẹ́ balógun ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù-obìnrin ti wọn gba ife-ẹ̀yẹ àgbáyé tí Olympic lọ́dún balógun ikọ̀ náà láti ọdún 1988 sí 1990.[8][9]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Rivers Angels win 2013 Federation Cup". M.news24.com. Retrieved 28 October 2014.
- ↑ "Women Football: Rivers Angels thrash Bayelsa in seasons' opener". Goal.com. Retrieved 28 October 2014.
- ↑ "Rivers Angels go five points clear" (in en-ZA). http://www.supersport.com/football/nigeria/news/140821/Rivers_Angels_go_five_points_clear.
- ↑ "Rivers Angels Football Club, Port Harcourt.". Facebook. Retrieved 28 October 2014.
- ↑ "Rivers Angels, Pelican Stars tussle for top spot" (in en-ZA). http://www.supersport.com/football/nigeria/news/140823/Rivers_Angels_Pelican_Stars_tussle_for_top_spot.
- ↑ "Archived copy". Archived from the original on 22 July 2015. Retrieved 27 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Proprietor of defunct Larry Angels, Larry Ezeh is no more". Kick442. 2021-01-14. Archived from the original on 10 October 2022. Retrieved 2021-01-18.
- ↑ "NWFL Official website". NFF. Archived from the original on 4 October 2017. Retrieved 27 September 2016.
- ↑ "Premier Captain Of Defunct Larry Angels Ajunwa Reacts On The Death Of Chief Larry Eze". Sports247. 2021-01-14.