Ẹran ìgbẹ́
Ìrísí
wọ́n mo ń sábà fi ẹran ìgbé láti mó jẹ́ kí ó bà jẹ́ | |
Alternative names | Wild meat, wild game |
---|---|
Main ingredients | Wildlife |
|
Ẹran ìgbẹ́ túmọ̀ s'àwọn ẹran tí wọ́n pa ní inú igbó ó sì tún túmọ̀ sí àwọn ẹranko tí àwọn ènìyàn ń jẹ nínú igbó, pàá pàá jù lọ, ní ilẹ̀ Adáwọ̀. Ẹran ìgbẹ́ jẹ́ orísun amú purotéènì ara fún àwọn ènìyàn Latin Amẹ́ríkà àti Asia.[1] ó tún jé orísun oúnjẹ fún àwọn ẹlòmíràn, pàá pàá jùlo àwọn tálíkà ní ìgbèríko.[2] Jíjẹ ẹran ìgbé wà lára ohun tí ó le ṣokùnfà àìsàn ara bi Ebola virus àti HIV wá láti ara ẹran ìgbé.[3][4][5]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nasi, R.; Brown, D.; Wilkie, D.; Bennett, E.; Tutin, C.; Van Tol, G.; Christophersen, T. (2008). Conservation and use of wildlife-based resources: the bushmeat crisis. CBD Technical Series no. 33. Montreal and Bogor: Secretariat of the Convention on Biological Diversity and Center for International Forestry Research (CIFOR). pp. 1–50. Archived from the original on 2014-10-30. https://web.archive.org/web/20141030093927/http://re.indiaenvironmentportal.org.in/files/Conservation%20and%20use%20of%20wildlife-based%20resources.pdf. Retrieved 2022-10-18.
- ↑ Bennett, E. L.; Blencowe, E.; Brandon, K.; Brown, D.; Burn, R. W.; Cowlishaw, G.; Davies, G.; Dublin, H. et al. (2007). "Hunting for consensus: reconciling bushmeat harvest, conservation, and development policy in West and Central Africa". Conservation Biology 21 (3): 884–887. doi:10.1111/j.1523-1739.2006.00595.x. PMID 17531066. https://www.researchgate.net/publication/6304848.
- ↑ Georges-Courbot, M. C.; Sanchez, A.; Lu, C. Y.; Baize, S.; Leroy, E.; Lansout-Soukate, J.; Tévi-Bénissan, C.; Georges, A. J. et al. (1997). "Isolation and phylogenetic characterization of Ebola viruses causing different outbreaks in Gabon". Emerging Infectious Diseases 3 (1): 59–62. doi:10.3201/eid0301.970107. PMC 2627600. PMID 9126445. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2627600.
- ↑ McMichael, A. J. (2002). "Population, environment, disease, and survival: past patterns, uncertain futures". The Lancet 359 (9312): 1145–1148. doi:10.1016/s0140-6736(02)08164-3. PMID 11943282. http://www3.carleton.ca/fecpl/courses/Reading%202.pdf.
- ↑ Karesh, W. B.; Noble, E. (2009). "The bushmeat trade: Increased opportunities for transmission of zoonotic disease". Mount Sinai Journal of Medicine: A Journal of Translational and Personalized Medicine 76 (5): 429–444. doi:10.1002/msj.20139. PMID 19787649.