Ọ̀mọ̀wé Shafi Lawal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
S. L. Edu
Fáìlì:Shafi Edu, 1987.jpg
Shafi Edu welcoming Prince Bernhard to Nigeria, 1987
Western Region Commissioner for Health and Social Services
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1911-01-07)Oṣù Kínní 7, 1911
Epe, Lagos State, Nigeria
AláìsíJanuary 8, 2002(2002-01-08) (ọmọ ọdún 91)
Ikoyi, Lagos, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian

Ọ̀mọ̀wé Ṣháfì Lawal tí a mọ̀ sí Ṣ.L Edu ni a bí ní ọdún 1911 tí ó sì kú ní ọdún 2002 jẹ́ oníṣòwò ìlúmọ̀ọ́ká àti ajàfẹ́tọ̀ọ́agbègbè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí. Ó wá láti ìlú Ẹ̀pẹ́Ìpínlẹ̀ Èkó. Òun ni olùdásílẹ̀ ètò-ìṣúná ajàfẹ́tọ̀ọ́agbègbè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà èyí tí kìí ṣe tí ìjọba tí ó sì máa ń rí sí àwọn iṣẹ́ jíjàfẹ́tọ̀ọ́agbègbè.

Ayé Rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Ọ̀mọ̀wé Edu ní ìlú Ẹ̀pẹ́ sínú ìdílé olórogún ti Láwàní Edu àti Raliatu tí í ṣe ìyá rẹ̀. Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti ilée-kéú kí ó tó di pé wọ́n mu lọ sí ilé-ìwé Mùsùlùmí alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ìjọba ní ìlú Ẹ̀pẹ́. Ó parí ní ọdún 1927 ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùkọ́ ní ilé-ìwé náà.[1][2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "S. L. Edu: A life to remember - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2016-01-08. Retrieved 2019-12-29. 
  2. "Journey from Epe : biography of S.L. Edu in SearchWorks catalog". SearchWorks catalog. 2019-12-21. Retrieved 2019-12-29.