Ọ̀rọ̀:Àlọ́ Ìjàpá àti Àlákàn
Ìrísí
Àkíyèsí pàtàkì
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ kú iṣẹ́ takun takun Oníṣe: Zeemahgan fún àwọn alọ́ orísiríṣi tí ẹ ń kọ sí orí Wikipedia èdè Yorùbá. Àmọ́, báwo ni kò bá ṣe dára tó kí fi àwọn ìtọ́ka sí tí ó yẹ sí àwọn àyọkà náà kí ó lè mọ́yán lórí. Ẹ lè lo àwọn ìwé ìtàn tí ẹ ń ṣàmúlò gẹ́gẹ́ bí ìtọ́ka sí yín. Ó ṣeé ṣe kí olóòtú àgbà fún Wikipedia Yoruba ó pa awọn ojú-ewé yẹn rẹ́ bí ẹ kò bá tètè gbé ìgbésẹ̀ lórí àkíyèsí pàtàkì yí. Ẹ ṣeun.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 12:12, 17 Oṣù Kejìlá 2022 (UTC)