Ọ̀rọ̀:Àwọn Ẹ̀ka-èdè Yorùbá
Ìrísí
ÀKÍYÈSÍ
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ kúuṣẹ́ o. Ẹ jọ̀ọ́, ó dàbí ẹni pé ẹni tó dá ojú-ìwé yìí sílẹ̀ kàn gbé ọ̀rọ̀ láti inú ìwé kan sí ojú-ìwé yìí ni. Ǹjẹ́ èyí tọ̀nà? Waliyullah Tunde (ọ̀rọ̀) 16:50, 12 Oṣù Kínní 2022 (UTC)
- Káre jàre Oníṣe: Waliyullah Tunde fún àkíyèsí pàtàkì yí, kò tọ̀nà láti gbé ohun tí wọn kọ sílẹ̀ ní ojú-òpó kan tabí ojú ìwé tí wọ́n ti kọ jáde láì jọọ́ dára dára kí ó tó di wípé a lò ó sí orí ìwé Ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia èdè Yorùbá. Bí èyí bá wáyé, a ní láti àyọkà náà kọ ni kí a sì wá ìtọ́ka sí tó yanrantí gbè é lẹ́sẹ̀ níbi tí ó ti yẹ. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 21:38, 12 Oṣù Kínní 2022 (UTC)