Ọ̀rọ̀:Ẹri Jaga
Ìrísí
Àkíyèsí pàtàkì
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mo kí oníṣẹ́@Omo iya eleja kú iṣẹ́ takuntakun. Mo fẹ́ pe àkíyèsí rẹ sí ìlànà ìlò èdè rẹ nínú àyọkà yìí wípé ó kú díẹ̀ káàtó. Agbékalẹ̀ àyọkà náà mẹ́hẹ gidi gidi, ó sì yàtọ̀ sí bí Yorùbá ti ń sọ̀rọ̀ tàbí kọ èrò wọn sílẹ̀. Jọ̀wọ́, ṣe àtúnkọ àyọkà yìí. O ṣeun Agbalagba (ọ̀rọ̀) 03:53, 4 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- e̩ ṣeun púpò̩ @Agbalagba tí e̩ bá ṣàkíèsí àyọkà yìí dáadáa e̩ ri wípé iṣé̩ ọwó̩ google ni nípa ṣíṣe àtúntè̩ oun tí ènìyàn bá ko̩ látàrí wípé ẹ̀ro̩ àgbélétan ni mo lò fún ògbifò̩ náà, èyí sì lè ṣe̩lè̩ sí e̩niké̩ni pàápàá jùlo̩ tí keyboard ò bá ní ède Yoràbá télè.
- Ẹ ṣé modúpé̩ fún àkíyèsí yín, n ó ṣe àwọn àtúnṣe tí o ye̩. Omo iya eleja (ọ̀rọ̀) 20:24, 5 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
- Ó dára bẹ́ẹ̀Agbalagba (ọ̀rọ̀) 20:28, 7 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)