Ọ̀rọ̀:Dres the rapper
Ìrísí
Dres | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Andres Vargas-Titus |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Dres |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹta 1967 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Queens, New York, U.S. |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | Rapper, actor |
Years active | 1989–present |
Labels | Mercury/PolyGram Records Ground Control Records Tommy Boy Entertainment |
Associated acts | Black Sheep Native Tongues |
Andres "Dres" Vargas-Titus) (ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹta, ọjọ́ kejidinlogun, ọdún 1967) jẹ́ Òṣeré Hip hop ni orile Ede Amerika. Ó jẹ́ olori fún àwọn Òṣeré tí orúkọ ègbé wọn jẹ́ Alternate Hip hop duo Black sheep group, kí ó tó dá dúró.
Ìṣe
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Dres dá egbe Black sheep kalẹ ni 1989 pẹ̀lú Mista Lawnge. Àwọn mejeeji kọ́kọ́ ṣeré papọ ni 1991 tí wọn pé àkọlé orin wọn ní De La Soul. Ó kópa ńinu àwo orin tí àkọlé rẹ jẹ "Fanatic of The B word.[1]
Àwọn ère amohunmàwòrán tí ó kopa ninu rẹ
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Who's the Man? (1993) as Malik
- Once in the Life (2000) as Hector
- "Words Up!" a CBS Schoolbreak Special, Season 10, Episode 2 (1992) as Aeschylus
Ẹ wo
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Itọ́kasi
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]External links
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ẹ̀ka:
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- African-American male actors
- American male actors
- African-American male rappers
- American people of Puerto Rican descent
- Hispanic and Latino American rappers
- Five percenters
- Living people
- Tommy Boy Records artists
- Rappers from New York City
- 1967 births
- 21st-century American rappers
- 21st-century American male musicians
- 21st-century African-American musicians
- 20th-century African-American people