Jump to content

Ọ̀rọ̀:Han Hye-jin (oṣere)

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mo kí ọ kú iṣẹ́ takun takun oníṣẹ́@Adeseyeyoju Deborah, àmọ́ṣá, o nílò láti bójútó àwọn àyọkà rẹ dáradára nípa kíkọ àti ṣíṣe à̀gbékalẹ̀ èdè Yorùbá rẹ. Gbìyànjú kí o tún àyọkà yí kọ tàbí kí o ké sí oníṣẹ́ mìíràn kí wọn ó ràn ọ́ lọ́wọ́ bí o bá nílò ìrànwọ́ wọn lórí àgbékalẹ̀ èdè Yorùbá. Ṣáájú, n ó bá ọ tún àyọkà yí kọ kí ó lè dúró gẹ́gẹ́ bí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún ọ lórí ohun tí a ń retí lọ́dọ̀ rẹ lórí àwọn àyọkà tó o ó ma kọ sílẹ̀ lọ́jọ́ iwájú. O ṣeun púpọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 21:29, 2 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC)