Jump to content

Ọ̀rọ̀ Wikipedia:Ìbápàdé

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

E se afikun adugbo Ososami. E seun pupo fun ise opolo ti e se.

Ẹ kú iṣẹ́[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Mo fi asiko yi ki oníṣe:enitanade kú iṣẹ́ ọpọlọ. Bibiire1 (ọ̀rọ̀) 17:58, 19 Oṣù Kọkànlá 2022 (UTC)

Ẹ kú iṣẹ́ Ọ̀gá mi, ẹ kú ọjọ́ mẹta sà.
Mo fẹ́ tẹ àròkọ tuntun jáde, ṣùgbọ́n kò ì yé mi sí. Ẹ ràn mí lọ́wọ́ sà Enitanade (ọ̀rọ̀) 03:55, 20 Oṣù Kínní 2023 (UTC)