Jump to content

Ọ̀rọ̀ oníṣe:112.206.110.248

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìforúkọ sílẹ̀

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ kú dédé àsìkò yí. Mo ṣàkíyèsí àwọn iṣẹ́ takun takun tí ẹ ń ṣe lórí ìkanì Yorùbá Wikipedia fun ìgbà díẹ̀ sẹ́yìn, inú mi sì dún láti ri wípé ẹ ń ṣe àtúnṣe tí ó bójú mu sí àwọn àyọkà pẹ̀lú. Amọ́ ṣe, kò bá dara kí ẹ fi orúkọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oníṣẹ́ kí a lè dáyín mọ̀ ju báyí lọ. Ẹ tẹ̀ lè ojú òpó yí https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=P%C3%A0t%C3%A0k%C3%AC:CreateAccount&returnto=Oj%C3%BAew%C3%A9+%C3%80k%E1%BB%8D%CC%81k%E1%BB%8D%CC%81&campaign=loginCTA láti fi orúkọ yín sílẹ̀, ẹ ṣeun. Bí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ kan tàbí òmíràn, ẹ kàn sí mi. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 08:01, 25 Oṣù Kẹrin 2021 (UTC)


Ojúewé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ yìí wà fún oníṣe aláílórúkọ tí kò tíì dá àkópamọ́, tàbí tí kò lò ó rárá. Bí bẹ́ẹ̀ laṣe únlo àdírẹ́ẹ̀sì IP oníyenọ́mbà láti dáamọ̀. Irú àdírẹ́ẹ̀sì IP báun ṣeéṣe kó jẹ́ pínpínlò pẹ̀lú àwọn oníṣe míràn. Tó bá jẹ́ pé oníṣe aláìlórúkọ ni yín, tí ẹ sì rò pé wọ́n ùnsọ̀rọ̀ tí kò kàn yín sí i yín, ẹ jọ̀wọ́ ẹ dá àkópamọ́ kan tàbí kí ẹ forúkọ wọlẹ́ kó mọ́ baà sí ìdàrúpọ̀ lọ́jọ́ọwájú mọ́ àwọn oníṣe aláìlórúkọ mírán.