Jump to content

Ọ̀rọ̀ oníṣe:Adeogun Yetunde Basirat

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹkáàbọ̀!

Ẹpẹ̀lẹ́ o, Adeogun Yetunde Basirat,ẹkáàbọ̀ sí Yòrùbá Wikipedia!! Adúpẹ́ fún àfikún yín. Mo lérò wípé ẹ nífẹ́ sí kí ẹ wà níbí. Ẹwo àwọn oun tí a ṣètò sí ìsàlẹ̀ yìí bóyá ó lè wúlò fun yín:

Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rántí fi òǹtẹ̀ tẹ oun tí ẹ bá kọ sí ọ̀rọ̀ ojú ewé pẹ̀lú igun mẹ́rin (~~~~); èyí máa gbé orúkọ yín àti déètì jáde. Bí ẹ bá ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ẹ kàn sí mi, +/-, mo sì máa ràn yín lọ́wọ́, ẹkáàbọ̀! Agbalagba (ọ̀rọ̀) 08:39, 15 Oṣù Kẹrin 2024 (UTC) Ẹ ṣeun sir. Àmọ́ ohun tí ẹ̀ ń gbìyànjú láti sọ ò yé mi.