Jump to content

Ọ̀rọ̀ oníṣe:Ola10debo

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

A kí yín Oníṣẹ́ Ola10debo, ẹ kú ọmọọ́ṣe, inú wa dùn láti ri wípé ẹ ń gbìyànjú gidi láti fẹ ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia èdè Yorùbá siwájú si. Òṣùbà káre yín rèé...

Mo fẹ́ pe àkíyèsí yín si wípé kí ẹ gbìyànjú siwájú si láti ṣe ògbufọ̀ àpilẹ̀kọ Idoti omi tí ẹ dá sílẹ̀ pẹ̀lú èdè Yorùbá tó yanrantí kí ó lè ṣeé dùn únkà dára dára. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún akitiyan yín. Bí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ èyíkéyí, ẹ kàn sí mi nípa lílo ọ̀rọ̀.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 20:25, 12 Oṣù Kẹta 2022 (UTC)