Ọ̀rọ̀ oníṣe:Olabisi11
Ìrísí
Ẹ nlẹ́ Oníṣẹ́:Olabisi11, inú mi dùn wípé ẹ ń ṣe akitiyan láti mú ìdàgbà-sókè bá iwe ìmọ̀-ọ̀fẹ́. A kíi yín kú iṣẹ́ ribiribi. Síbẹ̀, mo ri wípé iṣẹ́ yín kú diẹ̀ káàtó nítorí bí ẹ ṣe ń ṣe ògbufọ̀ yín kò yàtọ̀ sí ti bọ́ọ̀tì. Bí ẹ bá fẹ́ nímọ̀ siwájú si nípa bí ẹ ṣe lè máa ṣe àfikún tó peregedé, ẹ lè kan sí mi fún ìtọ́ni. Lẹ́kan si, mo kí yín kú iṣẹ́. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 08:09, 19 Oṣù Kẹta 2021 (UTC)
Start a discussion with Olabisi11
Talk pages are where people discuss how to make content on Wikipedia the best that it can be. Start a new discussion to connect and collaborate with Olabisi11. What you say here will be public for others to see.