Ọ̀rọ̀ oníṣe:Sowoletoyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

E pele.

E jowo nigba ti e ba se atunse si ayoka, e je ki awon ajapo/links o wa. Demmy (ọ̀rọ̀)

.[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ n lẹ́ níbẹ̀ yẹn o! Ṣówọlétọ̀yín, a kí yín, a yìn yín, a lù yín lọ́gọ ẹnu. A ń ṣàkíyèsí gbogbo iṣẹ́ àti akitiyan yín lórí ìkànì yí, ó sì ń wú wa lórí gidi gidi. A rọ̀ yín kí ẹ máa wá lóòrè kóòrè láti máa tẹ̀ síwájú nínú ojúlówó iṣẹ́ tí ẹ ń ṣe. A dúpẹ́ púpọ̀. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 21:29, 18 Oṣù Kẹta 2020 (UTC)