Ọ̀rọ̀ oníṣe:Temiluv
Àkíyèsí pàtàkì
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Kú iṣẹ́ takuntakun @Temiluv, mo ri wípé o ṣẹ̀ṣẹ̀ dá àyọkà Garcinia cowa sílẹ̀ lòrí Wiki yí. Mo fẹ́ pè ẹ́ sí àkíyèsí ńlá kan ni. Mo ri wipe àyọkà yi jẹ èyí tí o fi irinṣẹ́ Googgle Translation kọ. Nigbàkúùgbà tí o bá lo iriṣẹ́ Google Translation yí, gbìyànjú kí o tun kọ sí èdè Yorùbá tó yanrantí. Ìwọ náà k̀ àyọkà rẹ wo nísàlẹ̀
(Garcinia cowa, ti a mọ n'igbagbọ bi eso cowa tabi mangosteen cowa jẹ ohun ọgbin lailai alawọ ewe pẹlu eso ti o jeun abinibi sí Asia, India, Bangladesh, Myanmar, Malaysia, Vietnam, Laos, Cambodia, ati guusu iwo oorun China . Igi náà ti wa ni Ikore lati inu igbẹ fún àwọn eso ati awọn ewe yi o jeun,ti a lọ ní agbègbè. Àwọn òdodo fẹ ofeefee ako ati abo awọn ododo ti yapa). Agbalagba (ọ̀rọ̀) 15:09, 12 Oṣù Kejìlá 2023 (UTC)