Ọ̀yọ́túnjí
Ìrísí
Oyotunji Apejopo awon kan ni yi ti won n gbe ede ati asa Yoruba laruge. Won pe ibi ti won wa ni The kingdom of Oyotunji, Box 51, Yoruba Village, South carolina 29941. Oruko Oba won ni H.R.H. Oba Oseijeman Adefunmi 1. Ile-Ife ni oba yii ti wa gba ade ni ojo karun-un osu kefa, odun 1981 ni aafin Oba Okunade Sijuwade, Olubushe Keji. Eyi si ni igba akoko ti eni ti kii se omo ile Naijiria yoo gba ade ni Ile-Ife. Orisirisi orisa ile Yoruba ni won n bo ni ibi yii.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- C.M. Hunt (1977), "Oyotunji Village: Yoruba Movement in America.", PhD Dissertation, West Virginia University.