Jump to content

Ọọ̀ni Ayetise

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ooni Ayetise ni Ọọ̀ni keje ti Ilé-Ifẹ̀ tó jẹ́ olórí ìbílẹ̀ ti Ilé-Ifẹ̀, tí ń ṣe orírun àwọn ọmọ Yorùbá. Lẹ́yìn tí Ọọ̀ni Obalufon Alayemore wàjà ni Ayetise jẹ oyè yìí, Ọọ̀ni Lajamisan sì ló jẹ Ọọ̀ni lẹ́yìn rẹ̀.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri&dq=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.