Ọbẹ yọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Ọbẹ yọ jẹ orukọ awọn ọbẹ to maa fa tikọ tabi yọ lọwọ. Bi apejuwe ọbẹ ila, ọbẹ ewedu, ọbẹ ọgbọnọ tabi eyi ti a nọ si apọn.[1] Ọbẹ yọjẹ ọbẹ to wọpọ ni apa ariwa iwọ irun ati apa ariwa busu orun ni ilẹ Naijiria. Irisi ọbẹ yi maa n ki, yo si ma yọbọlọ ti a ba njẹ yala pẹlu ṣibi tabi pẹlu ọwọ wa. Awọn ounjẹ ti an fi jẹ ọbẹ yọ ni an pe ni okele. Awọn ounjẹ bi fufu, iyan, amala, eba, ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Thrive No Matter What". Google Books. Retrieved 2018-10-15.