Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ọba Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó)
Ọba Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó, Karunwi III | |
---|---|
Ọba Osilẹ̀ ti Òke Ọnà | |
Born | 1938 |
Ọba Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó ni Osilẹ̀ ti Òkè Ọnà ni Ilẹ̀ Ẹ̀gbá. Òun ni bàbá tí ó bí sẹnetọ Lánre Tẹ́júoṣó.[1][2][3][4] Wọ́n bí Ọba Adédàpọ̀ Adèwálé sínú ẹbí Joseph Ṣómóyè Tẹ́júoṣó, nígbà tí orúkọ ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Esther Bísóyè Tẹ́júoṣó, ẹni tí ó jẹ́ ọmọọmọ fún Ọba Kárunwí Kínní ti Òkè Ọnà.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "HRH Adedapo Tejuosho Celebrates 75 In Egba". Channels TV. http://www.channelstv.com/2013/02/25/hrh-adedapo-tejuosho-celebrates-75-in-egba/. Retrieved March 2, 2017.
- ↑ "Dr. Adedapo Tejuoso gives away his Dear Daughter Princess Layebi in Marriage". Bella Naija. https://www.bellanaija.com/2017/01/oba-dr-adedapo-tejuoso-gives-away-his-dear-daughter-princess-layebi-in-marriage/. Retrieved March 2, 2017.
- ↑ "Meet Oba Adedapo Tejuoso’s 24 Children". https://entertainment.naij.com/502079-meet-oba-adedapo-tejuosos-24-children-photos.html. Retrieved March 2, 2017.
- ↑ Joseph A. Adeyemo (Rev. Dr.) (1999). Traditional Ruler Turned Evangelist. Indiana University (Faith Unity Press). p. 63. ISBN 978-9-7828-000-46. https://books.google.com/books?id=VsCOAAAAMAAJ&q=adedapo+adewale+tejuoso+tejuosho&dq=adedapo+adewale+tejuoso+tejuosho&hl=en&sa=X&ved=0ahUKEwiH_p-y0rfSAhVHBBoKHU1IAGoQ6AEIHTAB.