Jump to content

Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọba Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó, Karunwi III
Ọba Osilẹ̀ ti Òke Ọnà
Born 1938

Ọba Adédàpọ̀ Adéwálé Tẹ́júoṣó ni Osilẹ̀ ti Òkè Ọnà ni Ilẹ̀ Ẹ̀gbá. Òun ni bàbá tí ó bí sẹnetọ Lánre Tẹ́júoṣó.[1][2][3][4] Wọ́n bí Ọba Adédàpọ̀ Adèwálé sínú ẹbí Joseph Ṣómóyè Tẹ́júoṣó, nígbà tí orúkọ ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Esther Bísóyè Tẹ́júoṣó, ẹni tí ó jẹ́ ọmọọmọ fún Ọba Kárunwí Kínní ti Òkè Ọnà.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]