Ọdún Ọlọ́jọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
ọdún ọlọ́jọ̀
àwọn èrò ní ọdún ọlọ́jọ̀

Ọdún Ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún ìbílẹ̀ kan pàtàkì tí wọ́n máa ń ṣe ní Ilé-Ifẹ̀ ní ìpínlè Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọdún tí wọ́n máa ń ṣe ní Ilé-Ifẹ̀ láti ṣe ìrántí ọjọ́ akọ́dá ayé, èyí ni ọjọ́ tí Olódùmarè kọ́kọ́ dá ilé-ayé. Ìgbàgbọ́ àwọn tí wọ́n ń ṣodún Ọlọ́jọ́ ni pé, o jẹ́ ọdún tí wọ́n fi ń bọ Olódùmarè.[1].

Àwọn tó n se odún olọ́jọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ilé-Ifẹ̀ tí ó jẹ́ orísun Yorùbá ni ọdún yìí tí gbajúmọ̀ jùlọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé káàkiri àgbáyé níbi tí àwọn ọmọ Yorùbá bá wà ní wọ́n tí máa ń ṣe Ọdún Ọlọ́jọ́. [2]

Àkókò tí wọ́n máa n se odún olọ́jọ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oṣù kẹwàá ni wọ́n máa ń ṣe Ọdún Ọlọ́jọ́

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Olojo Festival … Grand celebration of rich Yoruba cultural heritage - The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2018-11-17. Retrieved 2019-11-12. 
  2. "Olojo festival begins in Ife - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. 2019-09-22. Retrieved 2019-11-12.