Ọjà Balógun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọjà Balógun Ajéníyà jẹ́ ọjà kan tí ó wà ní ere-kùṣù Ìpínlẹ̀ Èkó. [1] Ọjà yí kò ní atọ́nà ina pàtó, nítorí wípé ó wọnú pupọ̀ àwọn àdúgbò lọ́tún lósì ni. Ṣùgbọ́n, oríṣiríṣi aṣọ tàbí bàtà igbá-lódé èyíkéyí tí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ tàbí wà ni wọ́n yóò rí ra níbẹ̀. [2]

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó ti wáyé níbeẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn oríṣiríṣi ríṣi ìṣẹ̀lẹ̀ lò ti ṣẹ̀ ní, láìpẹ́ yí ni àwọn ìwé ìròyìn gbe wípé ìṣẹ̀ ina wáyé níbẹ̀, tí ó sì ṣọṣẹ́ gidi gidi. Pupọ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yí ni ó ma ń wáyé láti ọwọ́ àwọn ọmọ ènìyàn.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Fire guts Balogun Market in Lagos Island (PHOTOS)". YNaija. Isi Esene. 27 October 2012. Retrieved 9 July 2015. 
  2. "Balogun Market inferno consumes seven buildings, two collapse". Punch Newspapers. 2016-06-19. Retrieved 2020-01-30.