Ọjà Jànkara
Ìrísí
Ọjà Jànkara jẹ́ ọjà tí ó tóbi jùlọ ní ìpínlẹ̀ Èkó tí wọ́n ti ń ta oríṣríṣi ohun èlò bí aṣọ, Ìlẹ̀kẹ̀,[1]ẹ̀gbà ọrùn, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Jankara Market - Lagos, Nigeria Shopping". Lonely Planet. 2017-01-05. Retrieved 2019-12-16.