Jump to content

Olayemi Ogunwole

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ọláyẹmí Ògúnwọlé)
Olayemi Ogunwole
Olayemi Ogunwole popularly known as HoneyPot in Lagos, Nigeria
Alma materObafemi Awolowo University
ShowChat Hour
Station(s)102.3 MAX FM, Lagos
NetworkTVC Communications
Time slot8pm - 11pm (GMT +1), Mondays - Thursdays
ShowEntertainment Splash
Station(s)TV Continental
NetworkTVC Communications
Time slot1pm - 2pm (GMT +1), Mondays - Fridays
CountryNigeria
Previous show(s)Midday Belt

Ọláyẹmí Ògúnwọlé  jẹ́ gbajúgbajà pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ (Honey Pot) lórí èrò àsọ̀rọ̀-mágbèsì àti èrọ amóhùn-máwòrán TVC Communications ní ìpínlẹ̀ Èkó.[1]

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oníṣẹ́ (Honey Pot) kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì nílé ẹ̀kọ́ àgbà Ilé Ifẹ̀ Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Nàìjíríà.[2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìròyìn rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọláyẹmí bèrè iṣẹ́ ìròyìn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ lásìkò ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní OAU, Ilé-Ifẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùgbàlejò lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán NTA ti Ilé-Ifẹ̀ níbi tí ó tí ń darí ètò tí ó ń jẹ́ Fact Finding with Yemi. Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àjọ Orientation Broadcasting Service (OBS) nigba tí ó ń ṣe Àgùnbánirọ̀ National Youth Service Corps rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Anambra, Nàìjíríà.[4][5]

Lẹ́yìn tí ó parí Àgùnbánirọ̀ (NYSC), ó tè síwájú láti ṣe agbátẹrù  Bísí Ọlátilọ Show (BOS). Ó tún lọ sí ilé èkọ́ FRCN láti kẹ́kọ̀ọ́ síwájú si. Ó tún ṣiṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ Rock City 101.9 FM, ní Abẹ́òkúta, níbi tí ó tí ṣètò Rock Game tí ó sì tún jẹ́ aka ìròyìnÓ sì tún ṣiṣẹ́ ní Star 101.5 FM, níbi tí ó ti ṣ̀ètò Midday Belt tí ó sì tún ka ìròyìn ojoojúmọ́, ṣáájú kí ó tó ta àtapò sí ilé iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ Rainbow 94.1 FM, níbi tí ó ti jẹ́ ọ̀gá àgbà àwọn elétò ní ilé iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ Max FM  tí ó ń jẹ́ (Radio Continental) tẹ́lẹ̀.[6]

Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ mìíràn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Yàtọ̀ sí iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́,ó tún ti ṣe ìpolówó ọjà fún  Harpic, First Monie ti First Bank àti àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́jà mìíràn. Òun àti Ruggedman ni ó ṣagbá-tẹrù ìgbàlejò àmì ẹ̀yẹ ayẹyẹ City People Music Awards ní ọdún 2017.[7][8]

Àwọn àmì ẹyẹ fún ìdánimọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n fun ní àmì ìdánimọ̀ àtàtà Special Recognition Award fún iṣẹ́ ribi-ribi àti ipa mále gbàgbé rẹ̀ nínú iṣẹ́ ìjábọ̀ ìdárayá lórí àmóhùn-máwòrán pàá pàá jùlọ City People ní ọduń 2016.[9]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ajose, Kehinde. "There is no limit to how far women can rise in the media". Vanguard Nigeria. https://www.vanguardngr.com/2016/05/no-limit-far-women-can-rise-media/amp/. Retrieved 5 July 2018. 
  2. "- 102.3 Max FM". Archived from the original on 2018-01-08. Retrieved 2018-10-13. 
  3. Sokoya, Seye. "I’m comfortable with my body —Honey Pot". Nigerian Tribune. http://www.tribuneonlineng.com/110449/. Retrieved 5 July 2018. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. "Meet The Honey Pot of MaxFM , Olayemi Ogunwole - 102.3 Max FM". 7 April 2018. Archived from the original on 25 January 2021. Retrieved 13 October 2018. 
  5. Kehinde, Seye (31 July 2017). "I am a Happy-Go-Lucky Girl - Honeypot, TVC Entertainment Splash Presenter". City People online. http://www.citypeopleonline.com/happy-go-lucky-girl-honeypot-tvc-entertainment-splash-presenter/. Retrieved 5 July 2018. 
  6. Anonymous (25 October 2017). "TVC Communications launches 102.3 Max FM". The Guardian Nigeria (online). Archived from the original on 5 July 2018. https://web.archive.org/web/20180705150713/https://guardian.ng/features/tvc-communications-launches-102-3-max-fm/amp/. Retrieved 5 July 2018. 
  7. Webdesk (8 August 2017). "TVC OAP Honeypot and Ruggedman host City People music awards". TVC online. https://www.tvcontinental.tv/2017/08/tvc-oap-honeypot-ruggedman-host-city-people-music-awards/. Retrieved 5 July 2018. 
  8. City People (14 August 2017). "Music Stars Storm 2017 City People Music Awards Details of the Colourful Event in Lagos". City people online. http://www.citypeopleonline.com/music-stars-storm-2017-city-people-music-awards-details-colourful-event-lagos/. Retrieved 5 July 2018. 
  9. Webdesk (26 July 2016). "TVC rejoices with her presenter ‘HoneyPot’ as she bags award from City People". TVC online. https://www.tvcontinental.tv/2016/07/tvc-rejoices-presenter-honeypot-bags-award-city-people/. Retrieved 5 July 2018.