Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Obafemi Awolowo University)
Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀
Obafemi Awolowo University
MottoFor Learning and Culture
Established1962
TypePublic
Vice-ChancellorProfessor Mike O. Faborode
LocationIle-Ife, Osun, Naijiria
Former namesYunifásítì Ilé-Ifẹ̀
Website[1]

Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ jé yunifásitì ijoba apapo ni Naijiria to budo si Ile-Ife. Wón dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọdún 1961, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ níbẹ̀ ní oṣù Kẹwàá ọdún 1962[1]Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Obafemi Awolowo University (OAU)". Times Higher Education (THE). 2020-04-01. Retrieved 2020-07-01.