Ọpọlọ ènìyàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọpọlọ ènìyàn
Human brain and skull
Cerebral lobes: the frontal lobe (pink), parietal lobe (green) and occipital lobe (blue)
Details
PrecursorNeural tube
SystemCentral nervous system
Neuroimmune system
ArteryInternal carotid arteries, vertebral arteries
VeinInternal jugular vein, internal cerebral veins;
external veins: (superior, middle, and inferior cerebral veins), basal vein, and cerebellar veins
LatinCerebrum[1]
Greekἐγκέφαλος (enképhalos)[2]
Anatomical terminology

Ọpọlọ ènìyàn ni ẹ̀yà ara tí ó wà nínú orí ọmọnìyàn tí ó sì jẹ́ ọ̀gangan irinṣẹ́ tí ó ń ṣàkóso gbogbo iṣan inú ara ènìyàn pátá pátá, pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ egungun ẹ̀yìn.

Ọ̀nà tí ọpọlọ pín sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọpọlọ pín sí orísi ọ̀nà mẹ́ta:

  1. cerebrum,
  2. brainstem, àti
  3. cerebellum.

Ọpọlọ ni ohun tí ó ń ṣàkóso ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣesí àgọ́ ara, nípa ṣíse ìgbésẹ̀, sísopọ̀ àti ìṣàkóso gbogbo ohun tí ó bá ń ṣe gba inú àgọ́ ara kọjá lásìkò kan. Ó ma ń ṣe ìpinu lórí ohun-kóhun tó ṣẹ̀lẹ̀ sí ènìyàn, tí yóò sì jẹ́ kí gbogbo ara ó mọ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wó lọ́wọ́. Inú egungun agbárí ẹ̀nìyan ni ọpọlọ wà ní orí ènìyàn.

Sẹ̀ríbúrọ́ọ́mù ni ó jẹ́ ìpín ọpọlọ tí ó tóbi jùlọ nínú àwọn ìpín ọpọlọ ọmọnìyàn. Sẹ̀ríbúrọ́ọ̀mù yí náà tún wá pín sí oríṣi méjì, àwọn ni:

  • cerebral cortex, èyí ni ó dà bí awọ fẹ́lfẹ́ tí ó wà lókè tí ó sì bo white matter. Cotex yí ni ó tún pín sí neocortex àti allocortex tí ó sì kéré jùlọ

Èyíkeyì nínú àwọn ìpín ọpọlọ yí ni wọ́n so pọ̀ pẹ̀lú commissural nerve tracts, tí ó jẹ́ corpus callosum.

Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa ọpọlọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ̀ka ẹ̀kọ́ tí ó níṣe pẹ̀lú ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa ọpọlọ ni wọ́n ń pè ní neuroanatomy, nígbà tí ìkẹ́kọ̀ọ́ nípa bí ọpọlọ ṣe ń ṣiṣẹ́ ni wọ́n ń pè ní neuroscience. Oríṣiríṣi ìlànà ni wọ́n ń gbà kẹ́kọ̀ọ́ àtibṣe ìwádí nípa ọpọlọ, lára rẹ̀ ni Specimens láti ara àwọn ẹranko ni examined microscopically.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àdàkọ:Cite dictionary
  2. Àdàkọ:Cite dictionary
  3. Fan, Xue; Markram, Henry (2019-05-07). "A Brief History of Simulation Neuroscience". Frontiers in Neuroinformatics 13: 32. doi:10.3389/fninf.2019.00032. ISSN 1662-5196. PMC 6513977. PMID 31133838. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=6513977.