50 Cent

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
50 Cent
50 Cent at the 2009 American Music Awards
50 Cent at the 2009 American Music Awards
Background information
Orúkọ àbísọCurtis James Jackson III
Ọjọ́ìbíOṣù Keje 6, 1975 (1975-07-06) (ọmọ ọdún 47)
Ìbẹ̀rẹ̀South Jamaica, Queens, New York, I.A.A.
Irú orinHip hop
Occupation(s)Rapper
Years active1997–present
LabelsShady, Aftermath, Interscope
Associated actsG-Unit, Dr. Dre, Eminem, Sha Money XL
Website50cent.com

Curtis James Jackson III (ọjọ́ ìbí Oṣù Kéje 6, 1975), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ 50 Cent, jẹ́ ará Amẹ́ríkà rapper, olùtajà, olùdókòòwò, atọ́kùn àwo orin, àti òsèré. Ó gbajúmọ̀ lẹ́yìn ìgbà tí àwọn àwo rẹ̀ "Get Rich or Die Tryin'" (2003) ati "The Massacre" (2005) jade. "Get Rich or Die Tryin'" ti gba ìwé-ẹ̀rí platinum mẹ́jọ láti ọwọ́ RIAA.[1] Àwo rẹ̀ "The Massacre" gba ìwé-ẹ̀rí platinum máàrún láàtı ọwọ́ RIAA.[1]Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]