72F fusion protein vaccine

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

72F fusion protein vaccine jẹ́ àjẹsára tuberculosis tí Statens Serum Insitut (SSI) ṣẹ̀dá rẹ̀. 72F fusion protein yìí ní irú àwọn protein Rv0125 àti Rv1196 tí ó jẹyọ láti Mycobacterium tuberculosis. Wọ́n parí àgbéyẹ̀wò ìlera àkọ́kọ́ ní ọdún 2005 tí wọ́n sì ń dúró de àgbéyẹ̀wò ìlera ìkejì.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]