Jump to content

Aṣọ Àdìrẹ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A Nigerian woman wearing adire clothing

Aṣọ Àdìrẹ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn aṣọ ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá. Tọmọdé tàgbà ni ó ń wọ aṣọ àdìrẹ tí wọ́n ṣiṣẹ́ ọnà oríṣríṣi sí lára nílànà ìbílẹ̀, tí ó sì wà ní àwọ̀ oríṣríṣi sí.[1] [2]


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Norma Wolff. "Adire". Fashion History:Love to know. Retrieved 25 December 2014. 
  2. {{citeweb|url=http://www.vam.ac.uk/content/articles/a/adire-indigo-resist-dyed-cloth-from-yorubaland-nigeria/%7Ctitle=Adire[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] – Indigo Resist Dyed Cloth From Yorubaland, Nigeria|website=Vam|location=United Kingdom|accessdate=25 December 2014|date=2013