A. Faleye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Oluko ni eka-eko Ede ati Litireso Aafirika ni A. Faleye. Litireso apohun ni o ni ife si ju lo, ibe si ni pupo ninu awon ise re da le lori. Sasa ni ohun ti ko le pe, ijala ni o, alamo ni o, esa eegun ni o, gbogbo re ni o le pe daadaa.