Aarhus

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Århus
Århus city trafikhavn.jpg
Århus inner city in 1998, from the South Harbor side
Country  Denmark
Region Central Denmark Region
Municipality Aarhus Municipality
Ìtóbi[1]
 • Urban 91 km2 (35 sq mi)
 • Metro 9,997 km2 (3,860 sq mi)
 • Municipal 468 km2 (181 sq mi)
Agbéìlú (2010)[2],[1]
 • Ìgboro 242.914
 • Ìgboro density 2,636/km2 (6,830/sq mi)
 • Metro 1,228,398 (17 municipalities in East Jutland metropolitan area)
 • Metro density 123/km2 (320/sq mi)
 • Municipal 307,119
 • Municipal density 656/km2 (1,700/sq mi)
Time zone Central Europe Time (UTC+1)

Aarhus, tabi Århus (Àdàkọ:IPA-da), ni ilu titobijulo keji ni orile-ede Denmark, ilu titobijulo 99run ni Isokan Europe, ati ikefa-titobijulo ni arin awon orile-ede Nordiki. Gege bi ebute pataki ile Denmark, o budo si egbe ilaorun peninsula Jutland ni gbongan onijeografi ile Denmark.

Ìlú tó tóbii sèkejì ní ilè Denmark. Àwon okò ojú omi máa n gúlè sí ibè. Ó ní Yunifásítì kan. Àwon ènìyàn tí ó wà níbè ní 1955 jé 118, 943. Òun ni olú-ìlú A.Co ní Jutland.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]