Jump to content

Aaroni Uzodike

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́


Aaron Uzodike jẹ́ olóṣèlú àti aṣòfin ní orílè-èdè Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣíṣe gẹgẹbi Aṣoju Ìpínlẹ̀ kan, ni àgbègbè Aba North ti Ìpínlẹ̀ Abia ni Ile-igbimọ Aṣofin Ìpínlẹ̀. [1] [2]

Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹjọ ọdún 2023, Aaron Uzodike ti ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) ti bura fún gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlè Abia ni ìgbìmò kẹjọ lẹ́yìn tí ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn fagi lé olùdíje ègbè Labour Party, Destiny Nwagwu. [3] Bi o tilè je wi pe ilẹ̀ ẹjọ dajo fun Uzodike ni oṣù kẹwàá ọdún 2023, ṣùgbọ́n ti won sun ibura re ṣíwájú lati odo olori ile igbimo aṣòfin, Rt. Hon. Emmanuel Emeruwa, nit'ori ọrọ ile-ẹjọ ti nlọ lọwọ. [4] [5]