Jump to content

Abímbọ́lá fashola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Abímbọ́lá Fáṣhọlá Abímbọ́lá Fáṣhọlá (ọjọ́ ìbí 6 April 1965) Ó jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní tẹ́lẹ̀ àti ìyàwó Gómìnà àná fún Ìpínlẹ̀ Èkó Babatunde Fáṣhọlá. Abímbọ́lá Fáṣhọlá

Orúkọ Abímbọ́lá Emmanuela Fáṣhọlá Ọjọ́ ìbí April 1965 Ìbàdàn, ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Nàìjírià Orílẹ̀ èdè Nàìjírià Ọmọ ìlú Nàìjírià Iṣẹ́ politician​administrator​journalist Ọdún 1987–present Ọkọ Babatunde Fashola Website Official websites

Ìgbé ayé àti iṣẹ́

A bíi ní 6 April 1965, ní Ìbàdàn, olú ìlú Ọ̀yọ́ southwestern Nàìjírià.[2][3] Ó kẹ́kọ̀ọ́ Akọ̀wé ní the Lagoon Secretarial College ní Èkó, níbití ó tí gba diploma certificate. Ó tún padà gba ìwé ẹ̀rí ní Computer Science from the University of Lagos.[4] Ó ṣiṣé díẹ̀ gẹ́gẹ́bí akẹ́kọ̀ọ́ journalist at the Daily Sketch kí ó tó darapọ̀ mọ́ the services of the British Council ní 1987 sùgbọ́n ó fiṣẹ́ sílẹ ní 2006 nígbàtí wọ́n fa ọkọ rẹ̀ Babátúndé Fáṣhọlá sílẹ gégébí flag bearer of his party and the governorship candidate of the defunct Action Congress of Nigeria.[5]

See also Kofoworola Bucknor Adejoke Orelope-Adefulire

Ìtọ́kasí

^ "My love story with gov Fashola-Lagos first lady". Mynewswatchtimesng​. Archived from the original on 23 April 2015. Retrieved 19 April 2015. ^ Clement Ejiofor. "Abimbola Fashola Shares Her Love Story". Legit. Retrieved 19 April 2015. ^ "ABIMBOLA FASHOLA, SYMBOL OF HUMILITY". This Day Live. Archived from the original on 27 April 2015. Retrieved 19 April 2015. ^ Aka, Jubril Olabode (2012). Nigerian Women of Distinction, Honour and Exemplary Presidential Qualities. ISBN 9781466915541. ^ "I don't have an eye for politics but .. Abimbola Fashola". Vanguard News. Retrieved 19 April 2015. Honorary titles Preceded by Oluremi Tinubu First Lady of Lagos State 2007-2015 Succeeded by Bolanle Ambode


This Nigerian biographical article is a stub. You can help Wikipedia by expanding it. Last edited on 29 October 2020, at 18:52

Content is available under CC BY-SA 3.0 unless otherwise noted. Privacy policy Terms of Use Desktop HomeRandomNearbyLog inSettingsDonateAbout WikipediaDisclaimers LanguageWatchEdit