Àwọn Erékùṣù Ábákò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Abaco Islands)
Jump to navigation Jump to search

Àwọn Akóìjánupọ̀: 26°28′N 77°05′W / 26.467°N 77.083°W / 26.467; -77.083

Abaco
Districts of Abacos Islands
The five administrative districts of the Abacos.
Jẹ́ọ́gráfì
Ibùdó Atlantic Ocean
Àgbájọ erékùṣù Àwọn Bàhámà
Ààlà 1,681 km2 (649 sq mi)
Orílẹ̀-èdè
Àwọn Bàhámà Àwọn Bàhámà
Erékùṣù Abaco
Ìlú tótóbijùlọ Marsh Harbour (pop. 5,728)
Demographics
Ìkún 14,100 (as of 2000)
Ìsúnmọ́ra ìkún 8.4 /km2 (21.8 /sq mi)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn Àwọn aláwọ̀dúdú ~50%, Àwọn aláwọ̀funfun ~50%
Abaco Islands

Àwọn Erékùṣù Ábákò (Abaco Islands) dubule si apaariwa awon Bahama, o si ni awon erekusu gangan Abako Ninla ati Abako Kenke, lapapo mo Wood Cay kekere, Elbow Cay, Lubbers Quarters Cay, Green Turtle Cay, Great Guana Cay, Castaway Cay, Man-o-War Cay, Stranger's Cay, Umbrella Cay, Walker's Cay, Little Grand Cay, ati Erekusu Moore. Fun imojuto, awon Erekusu Abako ni marun ninu awon Ipinaye ile awon Bahama 31: Ariwa Abako, Arin Abako, Guusu Abako, Erekusu Moore, ati Hope Town. Ninu awon ilu to wa ni awon erekusu na ni Marsh Harbour, Hope Town, Treasure Cay, Coopers Town, ati Cornishtown.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]